INTERGALACTIC LOOPHOLE DOCUMENT PDF Original - Free E-Book Download.Buddhas Book of Sleep: Sleep better in seven weeks with mindfulness meditation.Bi oro se ri ni awon orile-ede meji yii lo se ri ni awon orile-ede miran gbogbo ti won ti n wa epo kaakiri agbaye - yato si Amerika. Owo ti won n ri lati ibi ohun ti Oluwa fi jinki won wonyi ni won fi n pese ina ijoba, omi, eto ibara-eni-soro ati bee bee lo fun awon eniyan won.īee ni titi ti moto ati alupupu pelu keke won n rin ja gaara.
Bakan-naa, bi owo epo se n gbe owo lori loja agbaye ni awon ijoba wonyi n pin owo mayederun fun awon ara ilu won. Yato si eyi, idile kookan lo ni ile lori ti won si ni moto ti won fi n se ese rin. Yato si pe gbogbo omo ile Saudi ati Libiya n gba iwosan ati eko lofee, jala epo kan ko ju nnkan bi ogun naira o le die lo - bi a ba se owo won si Naira. Ile Naijiria nikan ni epo ti n je wahala laarin gbogbo orile-ede ti won ti n wa epo ni gbogbo agbaye. Gege bi ohun ti Olubadamoran pataki kan si Aare Obasanjo ti o bebe pe ki a mase daruko oun se so fun Oloye Gbode ijoba ti setan bayii lati mu ero re se nipa oro epo. Atipe bi o tile je pe won pin in lowo sise bee ni asiko ti a wi yii, kii se pe ijoba ti gbagbe oro naa rara. A o tun ranti pe oro yii da yanpanyanrin sile laarin ijoba apapo ati ajo osise Nigerian Labour Congress, NLC ti o fi aake kori pe ko gbodo si afiikun owo epo rara.Īsiko yii ni Aare Obasanjo se ileri pe ko ni si afiikun owo epo rara ni odun Ni asiko ti a wi yii, awon to mo oye oro labe ijoba so pe ogorun naira gan-an ni ijoba fee maa ta jala epo kan. A o tun se iranti pe ni odun ti jala owo epo fi joko si N65, nnkan bi ogorin lo koko lo.
Bi o tile je pe Aare ko so pe owo epo yoo le kun, ohun ti mimu owo iranwo kuro tumo si ni pe iye owo ti ijoba n ta epo sita fun ara-ilu ko ni iye ti o n taa tele. Nnkan bi aadota bilionu naira pere ni ijoba yoo maa fi se owo iranwo lati odun ti n bo lo. Gege bi Aare ti wi, owo iranwo ti ijoba n fi si ori epo ti awon omo Naijiria n lo je nnkan bi bilionu N Nitori eyi, ijoba yoo pase fun awon olokoowo ki won da si oro naa nigba ti ijoba. So Where Are We From Then? « ktravula – a travelogue!
Ona ti o gba soro ekunwo naa ni siso pe ijoba yoo se adinku owo iranwo subsidy ti o n fi si ori epo. Ilu Abuja lo ti so oro naa nigba ti o n se agbekale eto isuna ijoba fun odun ti a wa nibe yii Budget ni iwaju awon omo asofin apapo members of the National Assembly. Se a o kuku ranti pe Aare orile-ede yii, Ogagun Olusegun Obasanjo ti so lodun to koja pe owo epo yoo lo soke lati ibere odun yii lo. Ohun ti o mu eyi waye ni ipinnu ijoba lati se afiikun iye ti won n ta epo labele. Eekeji, bi o ba je pe loooto ni pe gbigbe epo pamo awon oluta-epo lo mu won, ki ni se ti ijoba ko se tu epo naa jade paapaa ni awon ile-itaepo ti e to ni kaakiri orile-ede yii nipase NNPC. Akoko, a ko tii gbo pe o fi iya kan dabi alara je ile-epo ti won gbamu pe o n gbe epo pamo. Ohun to fi han gbangba pe ai ri epo gbe jade lati ile-ise ijoba lo je ki epo won, ki i se gbigbe epo pamo, ni kikuna ijoba lati se nnkan gboogi lori oro naa lati bi ose mefa ti isoro yii ti bere. It's free to register here to get Book file PDF True Calling: Life and Times of Revd JA Okesiji, JP Pocket Guide. This Book have some digital formats such us :paperbook, ebook, kindle, epub, fb2 and another formats. Happy reading True Calling: Life and Times of Revd JA Okesiji, JP Bookeveryone.ĭownload file Free Book PDF True Calling: Life and Times of Revd JA Okesiji, JP at Complete PDF Library.
You can download and read online True Calling: Life and Times of Revd JA Okesiji, JP file PDF Book only if you are registered here.Īnd also you can download or read online all Book PDF file that related with True Calling: Life and Times of Revd JA Okesiji, JP book. Book file PDF easily for everyone and every device.